A-HEAD IN PUBLISHING
An authentic African Graphic Novel Series - Join Akin on his amazing journey in a historic, frictional Africa.
Ìwé ìtàn aláwòrán onísíséhìntèlé tiwa ntiwa - Tèlé Akin nínú ìrìn àjò tó lárinrin. Ìtàn àròsọ ayé àtíjọ́ ní ilẹ̀ adúláwọ̀ ni.
ERA OF DIAMONDS
An exciting African story full of action, comedy, suspense, culture, and many lessons to learn.
Join us in this exciting adventure in a world of diamonds.
ÀKÓKÒ Ọ̀ṢỌ́
Ìwé tó dùn. Ìwé tó lárinrin. Ìwé tó kọ́ni lẹ́ẹ̀kọ̀ọ́ nípa àṣà àti ìṣe àwọn èèyàn adúláwọ̀.
Ẹ wá bá wa kálọ nínú ìtàn amúnijókòómádìde nídì ẹ̀ títí tí yóò fi parí rẹ̀.
Reach out to us using the form below:
Ẹ lo abala tí a pèsè lábẹ́ láti fi bá wa sọ̀rọ̀:
Subscribe below and receive the full teaser in your mailbox:
Ẹ darapọ̀ mọ́ wa kẹ gba ìtàn ìtọ́lẹ́nuwò nípa Ọlọ́dẹ Ọ̀ṣọ́ sílẹ̀.